Ọga agba ati oludasilẹ ileeṣẹ Adrons iyen ileeṣẹ to ṣe e fọkantan ninu ilẹ tita,Aarẹ Emmanuelking Adetọla ti fi ẹmi imoore han sawọn oṣiṣẹẹ rẹ lasiko ọdun keresi yii,nipa fi fun wọn lẹbun owo,onjẹ ati awọn ẹbun amoriya miiran
Pẹlu idunnu ni ọpọ wọn fi dupẹ oore nla ti ọmọ bibi ipinlẹ Ogun naa ṣe fun wọn ,ti ẹ o ba gbagbe pe,ọsẹ to kọja lọ yii ni Aarẹ Emmanuelking ṣi fun awọn oniroyin to le ni igba ni ẹbun adiẹ meji ,apo irẹsi ati ororo fun enikọọkan wọn bẹẹni ọgbẹni Wọle tun gba ẹbun ọkọ bọgini lọ sile nigbati oniroyin meji mi in jẹ ẹbun foonu to le ni miliiọnu kan naira ati laputọọpu towo ẹ le ni miliọọnu meji iyẹn lẹyin oṣu mẹfa tawọn oniroyin jẹ ẹbun ọkọ ati ẹrọ ifọṣọ.
Ẹ ma gbagbe pe ilẹ ṣi wa ni tita o paapaa lasiko ọdun keresi yii bẹẹni ẹbun wa fawọn to ba ra ilẹ nieeṣẹ ADRONS,ẹbun bii ororo,ẹran agbo,adiẹ,irẹsi,ẹrọ ilọta,ẹrọ ifọṣọ atawọn ẹbun miiran,ilẹ wa nibikibi kaakiri orilẹede yii,tete kan si ọfiisi ADRONS to ba wa nitosi re,Adrons! ileeṣẹ to ṣe e gbojule ninu iṣẹ ilẹ tita,ADRONS!Araba ni baba.

No comments:
Post a Comment