Adura lawon ololufe Bisola Badmus to je oseretiata obinrin wa n fi ranse si i lasiko yii nitori aisan to n yo o lenu,Bisola to lomi lara daadaa tele ti ru sugbon ti igbagbo wa pe pelu adura Olorun yoo se asepe ise iyanu re ninu aye e,iya olomo kan naa to tun je okan ninu awon obinrin to bimo fun Oluaye fuji iyen olori omobaAkile Ijebu,Alaaji Wasiu Ayinde lawon ololufe re ti n fi adura ranse si bayii pe,ki Olodumare mu u larada laipe
Sunday, December 10, 2023
Home
Lagbo Osere
Olorun yoo fun Bisola Badmus iyawo Wasiu Ayinde ni alaafia to peye-Awon ololufe Bisola

Ẹka Iroyin
# Lagbo Osere
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Lagbo Osere
Labels:
Lagbo Osere
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment