Alaaji Sefiu Alao tun ti lo ṣere nilu Oyinbo o - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, December 8, 2023

Alaaji Sefiu Alao tun ti lo ṣere nilu Oyinbo o


O kere ju o ti to igba mẹfa lọdun yii ti baba oko laarin awọn onifuji iyẹn Alaaji Adekunle Ṣẹfiu ti lọ ṣere loke okun laarin ọdun yii,eyi ko le ma ri bẹẹ gẹgẹ bi awọn ololufẹ fuji ṣe mọ pe,Sẹfiu ko ṣe e fọwọ rọ sẹyin ta ba n sọrọ nipa olorin fuji to n kọrin ọgbọn pelu ohun to dun leti
Ọjọ diẹ ni baba oko tun fẹ lo ni Orile ede London ,ti yoo si pada sorile ede yii lopin ọsẹ,Baba Gaji to jẹ gbajumọ puromota ni Agbara Orin lọ kọrin fun ti a si gbọ pe owo tabua ni Sefiu pa nibi ode ere naa
Ọpọ ode ere lo tun ti wa nilẹ lọdun to n bọ ni orile ede yii ati oke okun fun Agbara orin fuji nitori orin ọgbọn ti baba oko n kọ lo mu u tayọ laarin awọn akẹgbẹẹ ẹ

No comments:

Post a Comment

Pages