Aare Emmanuelking oludasile ileese Adrons ki Gomina ipinle Ogun ku oriire - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Saturday, January 20, 2024

Aare Emmanuelking oludasile ileese Adrons ki Gomina ipinle Ogun ku oriire


Aarẹ Emmanuelking to je oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS Iyẹn ileeṣẹ to ṣiwaju tente nipa ilẹ tita kaakiri agbaye ti ki Gomina ipinlẹ Ogun ọmọọba Dapọ Abiọdun ku oriire ijawe olubori labe ẹgbẹ oselu APC ninu eto idibo to koja lo yii nipinle naa,Ni bayii ti omooba Abiodun ti gba lẹta lati kọọtu to ga julọ nipinlẹ naa ni Aarẹ Emmanuelking ti gba gomina nimoran lati maa ba iṣẹ rere rẹ lọ nipinlẹ naa.

No comments:

Post a Comment

Pages