Aarẹ Adetọla to jẹ oludasilẹ ileeṣẹ Adrons ti seranti awon akoni ologun to ti papoda ni orile ede yii
ọjọ ayajọ iranti ọdun awọn ologun to ti papoda to waye laipẹ yii ni ileeṣẹ to ṣe e gbojule nipa iṣẹ ilẹ ati ile tita naa iyẹn ADRONS ti seranti awon akoni ti won ti so emi won nu ki alaafia le joba ni orile ede yii
E ma gbagbe pe,ileese Adrons nikan lo se e fokantan ninu ise ilẹ ati ile tita kaakiri agbaye,ẹ kan si ọfiisi wọn to ba sunmọ yin fun alaye lẹkun rẹrẹ.ADRONS araba ni baba lọjọkọjọ

No comments:
Post a Comment