Awọn ọba alade gboṣuba kare lai fun ileeṣẹ ADRONS - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Wednesday, January 17, 2024

Awọn ọba alade gboṣuba kare lai fun ileeṣẹ ADRONS


Ọjọ keji ọdun 2012 ni ileeṣẹ Adrons iyẹn ileeṣẹ to n ta ilẹ fawọn eeyan lọna irọrun ti bẹrẹ iṣẹ ṣugbọn niṣe lo dabi ogun ọdun,Olumale ti Ṣimawa oloye Nasiru Awolaja lo sọrọ yii lasiko to n sọ nipa ileeṣẹ ADRONS,bee lo so pe ilu Simawa ni ileese naa ti koko bere katakara oro ile
Ọga agba ileeṣẹ Synergy Guards,oloye Oladeji Bolarinwa naa ti wa so pe oun le fowo soya pe Adron nikan ni ileese to se e gbojule ninu ise ile tita
Oludasile ileese Adrons oloye Adetola to kawe gboye nipa ile tita ati ohun ini ni yunifasiti ti tun wa fi n da opo eeyan loju pe,e o ni kabamo ti e ba ra ile nileese oun
Boya eyin fe mo siwaju si i nipa ileese naa tabi e fe ra ile,e tete lo si eyikeyi ofiisi won to ba wa nitosi yin,ADRONS araba ni baba lọjọkọjọ

No comments:

Post a Comment

Pages