Gbogbo awon to ri fidio ibi ti Destiny boy to je okan lara awon odomode olorin takasufe ti n dupe lowo Mayegun ile yoruba to tun je olori fawon onifuji,Alaaji Wasiu Ayinde Olasunkanmi Omogbolahan fun ebun owo milioonu mewa naira to fun un lasiko ti oun ati baba re,oloye Ifayomi Obaedu sabewo si Mayegun ni won ti n so pe iro nla ni,nitori Oluaye kala nipa oro owo ati pe ko le deedee fun eeyan lebun owo milioonu mewa.
Wednesday, January 17, 2024
Home
Lagbo Amuludun
Destiny boy olorin takasufe so pe,Wasiu Ayinde fun oun ni ebun owo milioonu mewa

Ẹka Iroyin
# Lagbo Amuludun
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Lagbo Amuludun
Labels:
Lagbo Amuludun
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment