Ileeṣẹ ADRONS fifẹhan sawọn onibaara wọn,ẹ wa wo ọna ti wọn gbe e gba - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Saturday, January 27, 2024

Ileeṣẹ ADRONS fifẹhan sawọn onibaara wọn,ẹ wa wo ọna ti wọn gbe e gba


Ifẹ lakọja ofin,eyi lo mu ileeṣẹ to ṣe e fọkan tan nipa ilẹ tita kaakiri orilẹ ede yii iyẹn ileeṣẹ Adrons sọ fawọn onibara rẹ pe,ẹdinwo wa lori ilẹ wọn to wa kaakiri ipinlẹ ni orilẹ ede yii,bẹẹni ẹbun bii,tẹlefisọn,ẹrọ ilọta igbalode,ẹrọ amu ounjẹ gbona,ẹrọ ifọṣọ atawọn ẹbun mi in wa fun ẹyin ti ẹ ba ra ilẹ lọdọ wọn,ẹ le sanwo diẹ ki ẹ dẹ maa san eyi to ku fun osu mẹrindinlogoji iyẹn ọdun mẹta gbako
Ilẹ wa ni Abẹokuta,Ifọ,Nassarawa,Ibeju,Epẹ,Ibadan,Abuja,Niger atawọn ibo mi in kaakiri orilẹ ede yii,ẹ ranti pe ileeṣẹ Adrons ṣetan lati fifẹhan sawọn onibara wọn paapaa lasiko ọdun ayajọ ololufẹ yii.Ohun idunnu lo jẹ fun ileeṣẹ Adrons pe ki ọpọ eeyan di onile lori
Ẹ tete lọ si ileeṣẹ ADRONS to ba wa nitosi yin lati di onile lori,ADRONS,adeori okin ko jọ tẹyẹkẹyẹ

No comments:

Post a Comment

Pages