O maṣe o!awọn ajinigbe pa ọba alade meji danu lọjọ kan ṣoṣo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Saturday, February 3, 2024

O maṣe o!awọn ajinigbe pa ọba alade meji danu lọjọ kan ṣoṣo


Awọn ajinigbe ti pa Onimọjo ti Imọjo ni ijọba ibilẹ Ọyẹ ati Ẹlẹsun ti Ẹsun Ekiti ọba David Ogunsakin danu lojo monde lasiko ti won n bo lati ibi ipade awon lobaloba nipinle Ekiti a gbo pe won sekupa oba Olatunde Samuel Olushola iyen Onimojo ati oba Ogunsakin leyin ti won gba awon ohun to wa lara won bii foonu,ileke olowo iyebiye ati owo lo,ti Alara ti Ara Ekiti oba Adebayo Fatoba si raye salo mo won lowo ni ti e,aarin Oke Ako ati Ipao Ekiti nijoba ibile Ajoni ikole nisele naa ti sele

No comments:

Post a Comment

Pages