Ọja Mandillas gbina nipinle Eko,awọn wẹda to n ṣiṣẹ nibẹ lo fa a - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, January 23, 2024

Ọja Mandillas gbina nipinle Eko,awọn wẹda to n ṣiṣẹ nibẹ lo fa a


ọpọ dukia ati ọja olowo iyebiye lo jona di eeru lasiko ti ina ṣẹyọ ninu odindi ṣọọbu to gbajumọ daadaa naa tọpọ awọn to ni ṣọọbu yii si wa ninu ibanujẹ bayii

No comments:

Post a Comment

Pages