Awọn ololufe Yọmi Fabiyi ti n ba a dupẹ bẹẹni wọn tun n ki i ku oriire ile tuntun to ṣẹṣẹ ṣi lẹyin irin ajo rẹ kaakiri gbogbo orilẹ ede(Tour)
Ohun to tun jẹ ki inu ọpọ ololufẹ Yọmi dun ni wipe,oun lo ni adugbo to kọ ile naa si,Adugbo Yọmi Fabiyi
Adura ti wa ni pe,ẹmi a lo ile naa ,wọn ko si ni sin oku ẹ sibẹ,ku oriire Yọmi ọmọ Fabiyi.
No comments:
Post a Comment