Ti a ba n sọrọ nipa Ayan,iyẹn awọn to n lu ilu fawọn olorin ,odu ni Queen Lias Abiodun eniti awon ololufe e mo si Ayangbajumo je,orile ede Amerika ni arewa eleyinju aanu obabinrin onilu yii n gbe nibe naa lo si ti n fise ilu dabira.
O ti wa gbe eto kan kale lasiko yii,eto naa wa fun awon agba onilu ti won ti fise ilu lilu jeun ri,Ayan-to-gbajumo loruko eto naa lori ero ayelujara ati telifisan,ẹ tẹ Ayan-to-gbajumo,kiakia lẹ o ri eto naa wo .
No comments:
Post a Comment