Oludasile ileeṣẹ to ṣe e fọkantan ninu ilẹ ati ile rira kaakiri agbaye iyẹn ileeṣẹ Adrons,Aarẹ Emmanuelking ti ki awon omo orile ede yii ku ajoyo odun bee lo bẹ wọn lati ni ifarada lasiko eto iṣejọba Aarẹ Tinubu to si so pe igba itura yoo de laipe
Bẹẹ lo tun ba awọn olugbe ipinlẹ Plateau daro fun ti iṣẹlẹ to mu ọpọ emi lọ lasiko ọdun keresi to kọja to ṣẹlẹ nipinlẹ naa.Aarẹ ti wa bẹ gbogbo awọn ọmọ bibi orile ede yii loke okun ati nitosi lati maa ranti orile ede wa ninu adura,ki iṣọkan ati ifẹ si wa nitori ibi ti ifẹ ba wa ni alaafia yoo ti jọba
Boya ẹyin ṣi fẹ mọ si i nipa ileeṣẹ ADRONS,ẹ lẹ kan si ọfiisi wọn to ba wa nitosi yin

No comments:
Post a Comment