Oludasile ijo harvester kaakiri agbaye,pasito Abolaji Idowu ti ranti awon to padanu ẹmi ati dukia wọn nipinlẹ Plateau lasiko odun keresi to kọja lọ yii ninu adura ati owo to le ni miliọọnu mẹwa,ninu ipade to waye ni iya ijọ rẹ to wa ni Lẹki ipinlẹ Eko ni iranṣẹ Ọlọrun yii ti kede pe,ijọ oun ran awọn olugbe ipinlẹ naa lọwọ.
Monday, January 1, 2024
Pasitọ Bọlaji Idowu ṣe iranlọwọ owo fawọn olugbe ipinlẹ Plateau
Oludasile ijo harvester kaakiri agbaye,pasito Abolaji Idowu ti ranti awon to padanu ẹmi ati dukia wọn nipinlẹ Plateau lasiko odun keresi to kọja lọ yii ninu adura ati owo to le ni miliọọnu mẹwa,ninu ipade to waye ni iya ijọ rẹ to wa ni Lẹki ipinlẹ Eko ni iranṣẹ Ọlọrun yii ti kede pe,ijọ oun ran awọn olugbe ipinlẹ naa lọwọ.
Ẹka Iroyin
# Esin
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Esin
Labels:
Esin
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment