Ẹfun abeedi!Kiniun pa ọgbẹni Ọlawuyi,oṣiṣẹ yunifasiti Ileifẹ - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, February 19, 2024

Ẹfun abeedi!Kiniun pa ọgbẹni Ọlawuyi,oṣiṣẹ yunifasiti Ileifẹ


inu ibanujẹ lawọn mọlebi oloogbe Olawuyi to jẹ oṣiṣẹ ni yunifasiti Ọbafẹmi Awolọwọ wa lasiko yii pẹlu bi kiniun ọdun mẹsan ṣe fa ọgbèni naa ya pẹrẹpẹrẹ lasiko to n tọju wọn ,a gbọ pe lati kekere ni ọgbẹni yii ti n tọju awọn kiniun yii ki ọrọ naa to o yiwọ loni ọjọ aje monde

No comments:

Post a Comment

Pages