Ikunlẹ abiamọ o!awon fulani daran daran pa pasito Ṣẹgun danu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Saturday, February 3, 2024

Ikunlẹ abiamọ o!awon fulani daran daran pa pasito Ṣẹgun danu


Ìnu oko rẹ ni abule Gege nilu Ogbomọṣọ lawọn fulani ka pasitọ Ṣẹgun Adegboyega mọ ti wọn si da ẹmi iranṣẹ Ọlọrun naa legbodo,iroyin ayọ to wa tẹle e ni pe,ọwọ ikọ ọlọpaa ipinlẹ naa ti tẹ mẹta ninu wọn.Ki Ọlọrun ba wa dọwọ ibi duro ni orilẹede wa

No comments:

Post a Comment

Pages