Aarẹ Emmanuelking ṣedaro Olubadan to w'aja - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Saturday, March 16, 2024

Aarẹ Emmanuelking ṣedaro Olubadan to w'aja


Oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS iyẹn ileeṣẹ ton ta ilẹ lọna irọrun ti ṣedaro Olubadan ana to w'aja lojo tọside ọsẹ to kọja,Aarẹ Emmanuelking Adetola to tun jẹ Aarẹ Apesinọla fun gbogbo Ibadan lapapọ ti sọ pe,iku Olubadan ana jẹ ohun to ba ni lọkanjẹ pupọ nitori ọmọwe lọba to ti ṣiṣẹ rere nigba aye rẹ ni Ibadan
Ọjọ tọside to kọja ni oru mọju ni iṣẹlẹ agbọsọgbanu naa ṣẹlẹ pe,ọba Lekan Balogun Ali Okunmade keji ti lọ darapọ mọ awọn baba nla rẹ ni ọrun alakeji,kabiesi to jẹ balogun ilu Ibadan ko to o di Olubadan jẹ dokita ati ọmọwe,ti Aarẹ Adetọla iyẹn Aarẹ Apesinọla to jẹ oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS si ti n daro Olubadan ana bayii

No comments:

Post a Comment

Pages