Alaaji Babatunde Saheed iyẹn Oluọmọ Kutọnu ti sọ pe ohun to dara ni kawọn olowo ati bọrọkini maa ṣaanu awọn alaini ninu ati lẹyin Ramadn eyi lo mu ogbontarigi oniṣegun ibilẹ to tun jẹ Oluọmọ ni orilẹ ede Kutọnu fi onjẹ bii burẹdi,irẹsi tọrẹ lasiko yii.To si jẹ pe adura lawọn to jẹ ninu anfaani yii fi ranṣẹ si Oluọmọ Kotonu.
Saturday, March 16, 2024
ỌPẹ o Oluọmọ Kutọnu fawọn eeyan ni onjẹ ọfẹ lasiko Ramadan
Alaaji Babatunde Saheed iyẹn Oluọmọ Kutọnu ti sọ pe ohun to dara ni kawọn olowo ati bọrọkini maa ṣaanu awọn alaini ninu ati lẹyin Ramadn eyi lo mu ogbontarigi oniṣegun ibilẹ to tun jẹ Oluọmọ ni orilẹ ede Kutọnu fi onjẹ bii burẹdi,irẹsi tọrẹ lasiko yii.To si jẹ pe adura lawọn to jẹ ninu anfaani yii fi ranṣẹ si Oluọmọ Kotonu.
Ẹka Iroyin
# Esin
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Esin
Labels:
Esin
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment