Api baide Bobo,Ayinde Marshal - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Saturday, March 2, 2024

Api baide Bobo,Ayinde Marshal


Gbogbo ojo keta osu keta ni ojo ibi olori fawon onifuji ,iyen mayegun ile yoruba to tun je olori omooba Akile Ijebu,Alaaji Wasiu Ayinde Marshal,Oluaye fe pin ebun onje fawon opo ati alaini lodun yii ni pelu ipo tawon mekunnu wa ni orile ede yii lasiko yii,api baide tu yuu sir

No comments:

Post a Comment

Pages