Ileese Adrons ti ba ileese UICL dowopo nipinle Plateau - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Saturday, March 2, 2024

Ileese Adrons ti ba ileese UICL dowopo nipinle Plateau


Ileese to se fokan tan nidi ise ile tita,iyen ileese ADRONs ti sowopo pelu ileese kan lati oke okun,UICL lati so ipinle Plateau ni Jos di ilu oba,won se eyi lati je ki ohun gbogbo rorun fawon olugbe ipinle naa,beeni oludasile ileese naa Aare Emmanuelking ti so aye si wa fawon ololufe ileese naa pe ile wa ni tita nipinle naa ati kaakiri igun mererin orile ede yii.

No comments:

Post a Comment

Pages