Benson Akintoye okan lara oga onimoto ku sinu ijamba moto L'eko - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, March 8, 2024

Benson Akintoye okan lara oga onimoto ku sinu ijamba moto L'eko


Okan lara awon omoose Alaaji Oluomo Akinsanya ni oloogbe Toye Benson to nijamba oko lori afara keta nipinle Eko oju ese lo ti je ipe Olorun nitori ijamba naa po koja siso,adura wa ni pe ki Olorun tu awon ebi oloogbe ninu

No comments:

Post a Comment

Pages