Ẹlẹlẹ dupẹ lọwọ awọn ololufẹ ẹ ti wọn ba a ṣajọyọ ayẹyẹ ọjọ ibi ẹ - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, March 8, 2024

Ẹlẹlẹ dupẹ lọwọ awọn ololufẹ ẹ ti wọn ba a ṣajọyọ ayẹyẹ ọjọ ibi ẹ


Oloye Rafiu Oseni Ẹlẹlẹ ti fi asiko yii dupẹ lọwọ awọn ọrẹ,mọlẹbi atawọn alabaṣiṣẹ pọ ẹ fun aduroti ati adura wọn lori ẹ fun ti ayẹyẹ ọjọ ibi ẹ to waye lana iyẹn ọjọ keje oṣu keta ,apagunpọtẹ ilu Igbein ti wa ṣadura fawọn ololufẹ ẹ pe,ajọṣe awọn ko ni i bajẹ ati pe oju gbogbo wọn yoo maa rọdun,Ẹlẹlẹ api baide tuuu yuu lẹẹkan si,ẹni iyi ẹni ẹyẹ ọrẹ awọn ọdọ atawọn mẹkunnu

No comments:

Post a Comment

Pages