Gbogbo ayajo ojo kewa osu keta ni ojo ibi re,purodusa topo awon olorin fuji mo daadaa,baba rere fawon omo re,onigbagbo omoleyin Jesu,omooba Ademola Adelakun olowo ori Adebukola,adura wa ni pe emi e a sopo odun laye,iku ojiji ko ni pa e,emi e a tubo gun beeni gbogbo wahala re ninu aye yii ko ni ja si asan,api baide tuuu yuuuu sir.
Sunday, March 10, 2024
Api baide tuuu yuuuu omooba Ademola Davies Adelakun
Gbogbo ayajo ojo kewa osu keta ni ojo ibi re,purodusa topo awon olorin fuji mo daadaa,baba rere fawon omo re,onigbagbo omoleyin Jesu,omooba Ademola Adelakun olowo ori Adebukola,adura wa ni pe emi e a sopo odun laye,iku ojiji ko ni pa e,emi e a tubo gun beeni gbogbo wahala re ninu aye yii ko ni ja si asan,api baide tuuu yuuuu sir.
Ẹka Iroyin
# Iroyin
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Iroyin
Labels:
Iroyin
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment