Ileeṣẹ ADRONS gbe eto ironilagbara kalẹ lati sami ayẹyẹ ọdun awọn obinrin lagbaye - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, March 11, 2024

Ileeṣẹ ADRONS gbe eto ironilagbara kalẹ lati sami ayẹyẹ ọdun awọn obinrin lagbaye


Ìleeṣẹ ADRONS iyẹn ileeṣẹ to ṣe e fi ọkan tan ninu ilẹ ati ile tita ti gbe eto ironilagbara kalẹ fawọn obinrin lati sami ọjọ ayajọ ọdun awọn obinrin lagbaye,wọn lọ si ile iwosan ijọba to wa ni LASUTH nipinlẹ Eko,aṣoju iyawo oludasilẹ ileeṣẹ naa lo lọ ṣoju Olori Aderonkẹ Emmanuelking,nigbati aṣoju iyawo Aarẹ Emmanuelking iyẹn arabinrin Ajobo Adenikẹ lo ti sọ pe ,oun mu kiki wa latọdo oloro Aderonkẹ fawọn obinrin to wa ninu ọgba ile iwosan lọjọ naa to si sọ pe,ileeṣẹ ADRONS ti ṣẹtan lati sanwo itọju ọpọ obinrin atawọn ọmọde ti wọn si mu ileri naa ṣẹ loju ẹsẹ nibẹ,bẹẹni wọn ti ṣeto lati pese eto idokowo fun pupọ ninu wọn.
Pẹlu arabinrin Ajobo lọjọ naa nii,iyaafin Amina Haastrup Olaniyan ati iyaafin Ihuoma Azuru .

No comments:

Post a Comment

Pages