Ijọ Genesis Global gbe isọji iṣọ oru alagbara kalẹ - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Wednesday, March 13, 2024

Ijọ Genesis Global gbe isọji iṣọ oru alagbara kalẹ


Olu ijọ wọn to wa ni Alakukọ ipinlẹ Eko nisọji agbayanu to tun jẹ iṣọ oru yoo ti waye lọjọ kokanlelọgbọn oṣu kẹta ti a wa ninu ẹ yii nibiti oludasilẹ ijọ naa,oluṣọ Ọladele isreal Genesis yoo ti fi adura yanju iṣoro ọpọ eeyan,Jesu n reti ẹ nibẹ.

No comments:

Post a Comment

Pages