Ọjọ tọside ọsẹ yii ni ọjọ ibi Alaaji Rafiu Oseni Ẹlẹlẹ - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Tuesday, March 5, 2024

Ọjọ tọside ọsẹ yii ni ọjọ ibi Alaaji Rafiu Oseni Ẹlẹlẹ


Ẹrin lo gba ẹẹkẹ ọmọ ọlọjọ ibi,ọjọ toside yii ni ayajọ ọjọ ibi Oloye Rafiu Oseni Ẹlelẹ Mowe Nation,ẹmi ẹ a ṣọpọ ọdun laye ọrẹ awọn ọdọ,alaafia ati ilera pipe lo maa a fi lo ọjọ aye rẹ.

No comments:

Post a Comment

Pages