Gbogbo ojo keje osu keta layajo ojo ibi Oloye Rafiu Oseni Okanlawon eniti awon ololufe e mo si Elele,oun naa tun ni ajagunpote gbogbo Igbein nipinle Ogun,ona oto ni alase ati oludari ileese Elele Real Advanced Estate iyen ileese to n ta ile ati ile lona irorun fun awon mekunnu gbe ayeye ojo ibi re odun yii gba pelu bo se lo sile awon omo alailobi to wa ni Ota ipinle Ogun to si fun won ni onje bii iresi,kositaadi,indomie,iledi fawon ewe(pampers)bisikiiti,ose iwe,ose ifoso,juisi atawon ohun miran ti enu n je
Ololufe awon odo to fi agbegbe Mowe ibafo sebugbe yii ti wa so pe,ife awon omode ati odo lo wa lokan oun bee lo ti gba awon odo nimoran lati mojuto iwe won nitori awon ni ogo ojo ola orile ede yii,api baide tuuu yuuu sir Oloye Elele baba alaanu awon mekunnu.

No comments:
Post a Comment