Oga agba ati oludasile ileese Adrons iyen ileese to se e fokan tan ninu ka ta ojulowo ile fawon eeyan,Aare Emmanuelking ti mo riri awon onibara e to si dupe lowo won nipa pipe apeje ti inu gbogbo awon eeyan yii si dun ,lasiko ti okan ninu won n ba wa soro lo ti so pe,oun ko kabamo pe oun ra ile nileese Adrons rara
Aye si wa beeni ileese Adrons si ni awon ile ati ile to fini lokan bale,boya eyin fe ba won dowo po e tete lo si eyikeyi ofiisi won to ba sunmo yin 

No comments:
Post a Comment