Ilu Makun Omi nipinlẹ Ogun maa mi titi lọjọ kọkandinlogun oṣu karun ọdun yii,lọjọ naa ni kabiesi Alayeluwa ,Ọba Kazeem Adeshina Salami ,Osobia ti Makun Omi ilufemiloye kinni,maa ja ewe oye Ba'aroyin ti ilu Makun Omi le ogbontarigi oniroyin to je oludasile iwe iroyin Islander ,Alaaji Ola Mohammed lori.
Oluaye fuji,olori omooba Akile Ijebu,Alaaji Wasiu Ayinde ni yoo dalubole lojo naa,tawon borokini ati eeyan pataki lawujo yoo si wa nikale lati ye ,Alaaji Islander to je amugbalegbe nipa eto iroyin fun Oba orin Saheed Osupa si lojo naa
Baba oloye tuntun ti wa je ko di mimo pe,gbogbo awon ololufe oun ni inu oun yoo dun lati ri lojo naa.
No comments:
Post a Comment