Ileese to se e fokan tan ninu ile ati ìlẹ tita lọna irorun nni iyen ileese ADRONS ti n ki awon osise kaakiri ku ti ayajo ojo osise to waye loni in ojo kinni osu karun un,ti won si n gbadura pe ,emi won yoo se opo e laye
Boya iwo si fe mo si i nipa ileese adrons abi o fe ba won dowopo,o le kan si okan ninu ofiisi won to ba sunmo e ,ADRONS araba ni baba nipa ile ati ilẹ tita
No comments:
Post a Comment