Ọpẹ o !Oluọmọ Kutonu ṣile awoṣifila si Orilẹ ede Kutọnu - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Wednesday, May 8, 2024

Ọpẹ o !Oluọmọ Kutonu ṣile awoṣifila si Orilẹ ede Kutọnu


Gbogbo awọn ololufẹ Alaaji Babatunde Saheed iyẹn Oluọmọ Kutọnu ni wọn ti n ba baba alaanu mẹkunnu naa dupẹ fun ti ile nla to ṣẹṣẹ ṣi ni orilẹ ede Kutọnu,awa naa n ki yin ku oriire o,ọrẹ awọn oniroyin ẹmi yin a lo ile naa pẹ titi

No comments:

Post a Comment

Pages