Gbogbo awon ololufe Alaaji Saheed Babatunde iyen Oluomo Kutonu ni won ti n ba a sajoyo ile tuntun ti alfa nla to je omo bibi ilu Ilorin yii to sese ko si agbegbe G,R,A nilu Oshogbo iyen adugbo to je pe awon olowo ati borokini lawujo n gbe
Oluomo Kutonu to je okan ninu awon onisegun ibile to n fi ewe ati egbo se oogun nilana tawon oloyinbo ti wa so pe oun dupe lowo Olorun fun aseyori ile nla yii .Adura wa ni pe emi yin a lo ile naa,Oluomo ore awon oniroyin,baba alaanu awon mekunnu,emi yin a lo ile naa lase Olodumare.
No comments:
Post a Comment