Oba Makun Omi fi Otunba Gbenga Daniel atiyawo e joye - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Wednesday, May 15, 2024

Oba Makun Omi fi Otunba Gbenga Daniel atiyawo e joye


Oba Kazeem Salami ti ilu Makun Omi nipinle Ogun ti foye Baamofin ilu e da gomina ana nipinle naa,Otunba Gbenga Daniel lola,beeni Yeye Olufunke Daniel yoo di Yeye Bamoofin ilu Makun omi lojo kokandinlogun osu karun un yii
Onorebu Adesegun Adekoya yoo di Bobajolu tilu Makun Omi ,ti Alaaji Ola Mohammed oludasile iwe iroyin Islander ni ewe oye Baaroyin yoo kan lori lojo naa
Oluaye fuji ni yoo dalubole fawon ololufe ilu Makun omi. 




No comments:

Post a Comment

Pages