Nipinle Ondo,Oyo,Ogun eeyan metala lo ku lasiko odun ileya - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, June 18, 2024

Nipinle Ondo,Oyo,Ogun eeyan metala lo ku lasiko odun ileya


Inu ijamba oko to waye kaakiri awon ipinle meta yii,ipinle Oyo,Ogun ati Ondo a gbo pe eeyan metala lo ku sinu ijamba oko ti eeyan mejidinlogorin si farapa,adura wa ni pe ,aabo Olorun yoo maa daju lori wa.Amin

No comments:

Post a Comment

Pages