O mase o,akekoo Adekunle Ajasin nipinle Ondo pokunso - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, June 18, 2024

O mase o,akekoo Adekunle Ajasin nipinle Ondo pokunso


Ayandare Dupe loruko arewa obinrin to wa ni ipele karun un ni yunifasiti Adekunle Ajasin nipinle Ondo ti a si gbo pe leyin to de lati iso oru laaro ojo monde ojo keji ileya lo pokunso,agbenuso ileese olopaa ipinle naa,Funmi Odunlami fidi isele naa mule to si so pe iwadi n lo lori idi ti omobinrin naa fi pokunso.

No comments:

Post a Comment

Pages