Inu idunnu lawọn mọlẹbi awọn ọdọ to janfaani ninu eto ironilagbara ti ileeṣẹ ADRONS ṣe fawọn ọdọ to le ni ẹgbẹrun mẹta gbe kalẹ ,ọjọ mẹta gbako ni eto to bẹrẹ lati ọjọ tọside ọjọbọ ,iyẹn ọjọ kẹẹdogun oṣu kẹjọ titi de ọjọ kẹtadinlogun oṣu naa.
Ọjọ mẹta yii lawọn ọdọ fi gba idanilẹkọ lori bi wọn ṣe le wulo fawọn obi,awujọ ati orilẹ ede lapapọ,lasiko ti oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS n ba awọn ọdọ yii sọrọ ni Aarẹ Emmanuelking Adetola ti soro lori akori eto to n je'Recharged National Convention'pe,ohun to dara ni ki ọdọ wulo fun awujọ ati fun ara ẹ pẹlu.
Apesinọla ilu Ibadan ,Aarẹ Adetọla tun sọ pe,gẹgẹ bii ogo ọjọ ọla orilẹ ede yii,o yẹ ki awọn ọdọ tete ṣawari ara wọn ki wọn si lo ẹbun ti wọn ba ni lati gbe ogo ọjọ iwaju orilẹ ede yii ga.
Inu awọn ọdọ to kopa ninu eto naa dun lẹyin ọjọ mẹta ti wọn fi gba idanilẹkọ ti wọn si pada sile wọn bii 'ẹda tuntun pẹlu imọ tuntun'
E ma gbagbe pe ,ileese Adrons nikan ni ileese to se e fokan tan ninu ilẹ rira,ti ẹyin naa yoo di onile lori lọna irọrun laarin oṣu perente,boya ẹ fẹ mọ si i nipa bi ẹ ṣe le dowopọ pẹlu ileeṣẹ ADRONS,e pe nomba yii,08138432335.ADRONS araba ni baba lọjọkọjọ.
No comments:
Post a Comment