ADRONS ti di araba ninu ilẹ ati ile tita - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, August 19, 2024

ADRONS ti di araba ninu ilẹ ati ile tita


Agbalẹtu loootọ ti a ba n sọrọ nipa ileeṣẹ to fini lọkan balẹ ninu karakata ilè ati ilẹ,ohun to jẹ ki ileeṣẹ ADRONS da yatọ laarin awọn akẹgbẹẹ ni pe,oye ohun tawọn onibara wọn fẹ ma n ye wọn ,to si jẹ pe,ohun ti onibara yii ba fẹ ni wọn yoo pese fun un lọna irọrun.
Oludasilẹ ati ọga agba ileeṣẹ ADRONS,Aarẹ Adetọla Emmanuelking,nigbagbo pe,ko si eeyan ti ko le di onile lori ati ibugbe to dara lo ye kawon olugbe orile ede yii maa gbe pelu owo ti ko gara.
O ma n so lopo igba pe,idile ti o ti jade ko so pe ki iwo naa ma di onile lori,eyi lo mu gbajumo onisowo ile yii se ilana bi o se le di onile lasiko ti ohun gbogbo ri bakan ni orile ede wa .
Ile si wa ni,Townpark and garden Emuren imota,Eko city park and garden Lekki Epe,Grandview park and garden Atan Ota,Treasure park and garden shimawa,Rehoboth park and garden Ibeju Lekki.
Ko wa si ibikibi ti e fe ra ile si ni orile ede yii ti ileese Adrons ko ni i mu yin de,ti ileese naa yoo si gba yin nimoran nipa ile ati ilẹ ti ẹ niilo,yatọ si pe ileese to se e fokan tan ni won,opo eto bii ,ironilagbara fawon odo,ipese eko ofe,idokowo ti ko gara ju fawon arugbo ni ileese yii n pese fawon onibara won.
Tete kan si ileese Adrons to ba sunmo e lati tete di onile lori,ADRONS araba ni baba loootọ

No comments:

Post a Comment

Pages