Ọpẹ o !ileeṣẹ ADRONS ṣeto 'Ogun ini mi sori ilẹ baba mi' - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Thursday, August 22, 2024

Ọpẹ o !ileeṣẹ ADRONS ṣeto 'Ogun ini mi sori ilẹ baba mi'


Ọga laarin awọn oniṣowo ilẹ lorilẹ ede yii ni ileeṣẹ ADRONS jẹ,odu ni ki n ṣaimọ oloko
Iroyin ayọ to tun wa gba igboro lasiko yii ni pe,ileeṣẹ alalubarika yii ti gbe eto'ori ilẹ baba mi 'kalẹ.
O tumọ si pe,ibikibi ti o ba n gbe lorigun mẹrẹẹrin agbaye,o le di onile lori nilu abinibi ẹ lai ṣe wahala
Gbogbo eyin ti e n gbe oke okun,anfani lati ra ile wa,ti eyin naa le fi yangan pe,'ẹ nile lori ilẹ baba yin.
Anfaani to pọ lo wa ti ẹ ba ra ilẹ nileeṣẹ ADRONS,disikanti wa lori ile ti e ba ra,ipele marun un lo wa pelu.
O le fi oruko e so adugbo ti o ba n gbe,ileese Adrons yoo salaye bi eyi yoo se rorun fun yin,onte latodo ijoba apapo.
E ma gbagbe pe,ebun wa nipele nipele ti e ba ti ra ile nileese ADRONS,ohun to dara ni ki obi fogun rere sile fawon omo.
Ojoojumo ni ile n gbowo lori si i,o le ra ile lati ko ile,gbin ohun ogbin,ko ileese ati beebeelo.
Tete lo si ileese Adrons to ba wa nitosi e nitori aye wa lati sanwo fun osu merinlelogun leyin eyi ile naa ti di ti e ni bee lawon ebun wa fawon onibara won
O le pe,Adeboye Abiodun 
Adeboye Abiodun
Mnipr,Acicrm
Digitaloperation and media relation officer
Adrons Homes and properties
08138432335

No comments:

Post a Comment

Pages