Awọn ohun to yẹ ki o mọ nipa'Lemon friday promo'ti ileeṣẹ ADRONS n ṣe re e - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Monday, October 28, 2024

Awọn ohun to yẹ ki o mọ nipa'Lemon friday promo'ti ileeṣẹ ADRONS n ṣe re e


Agbolade Toyin
Ọdọọdun nileeṣẹ ADRONS iyẹn ileeṣẹ to ṣe e fọkantan ninu rira ati kikọ ile fawọn onibara wọn ma n gbe eto'Lemon friday promo'kale ti eto yii si ti so opo eeyan di onile lori.
Lemon friday promo ti todun yii tun wa gba ona miiran yo ,eto to n lo lowo yii ni awon anfaani to po ninu,lati le mu gbogbo eeyan di onile lori lo mu ileese Adrons se awon eto bii,
**Edinwo lori awon ile ti e ba ra lowo won,ile fun ile kiko,ileese kiko,ile fun ise agbe,ati ibugbe kiko wa fun tita pelu edinwo lori awon ile naa.
**San diedie fun ogota osu gbako,ti e ba ti sanwo naa tan ile ti di tiyin niyen.
**Jije ebun yanturu bii,eran agbo,iresi,masiini iloso ati eyi to n fo aso mo,pelu opo ebun lo wa nile ti o ba wa ra ile nileese won.
**Ko si ipinle ti e fe ra ile si ti ileese adron ko ni fun yin nile si,ipinle Ogun,Eko,Osun,Jos,Nasarawa,Abuja,Ekiti,Ibadan ati awon ipinle to wa nigun mereerin orile ede yii ni ile won wa fun tita.
**Ileese yii yoo ba a yin se awon iwe ile bii c of o,atawon iwe to ku ti ko ni si idaamu latodo ijoba fun yin rara.
**Adrons yoo gba yin nimoran ti e ba salaye ohun ti e fe se lori ile naa fun won,adugbo to dara lati se irufe ohun ti e ra ile nitori .
**E o gbadun won yala o je igba akoko ti e fe ra ile nileese won nitori iberu Olorun ni ileese yii fi n ta ile bee lo je pe,ki e le di onile lori lo je won logun ju.
Boya iwo fe mo si i nipa ileese Adrons,tete kan si eyikeyi ofiisi won to ba wa nitosi odo e.

No comments:

Post a Comment

Pages