Toyin Agbolade
Inu gbogbo awon omo bibi ilu Oro nijoba ibile Irepodun nipinle Kwara Ilorin lo n dun lasiko yii pelu bi ilu naa se ni oba alade tuntun.
Oba Joel Olaniyi Oyatoye (baba aṣa) ni oba alade tuntun ,Oloro ti Oro nipinle Kwara je omowe,olopolo pipe to si setan lati mu itesiwaju ati awon ohun gidi wo inu ilu naa lasiko to di oba.
Kabiesi igba yin a tu ilu Oro lara ,beeni ade yoo pe lori.
No comments:
Post a Comment