O mase o!Baba Banji Iyaniwura,gbajumo onkowe itan atakoroyin jade laye - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, February 7, 2025

O mase o!Baba Banji Iyaniwura,gbajumo onkowe itan atakoroyin jade laye


Ojo eti yii ni iroyin agbosogbanu naa gba igboro pe,baba Banji Iyaniwura topo mo si baba Binutiri ti jade laye,opo iwe itan lede yoruba ni baba to je akoroyin pelu ileese iwe iroyin alariya oodua nigba kan ko,eni ogorin odun ni baba ki iku to o de.

No comments:

Post a Comment

Pages