Ti a ba n sọ nipa ileeṣẹ to ṣe e fọkan tan ninu ilẹ ati ile gbigbe tita,odu ni ileeṣẹ ADRON kaakiri orilẹ ede yii,ọdun yii gan an lo pe ọdun kẹtala ti wọn da ileeṣẹ naa silẹ
Oludasilẹ ileeṣẹ ADRON,Aarẹ Emmauelking Adetola wa dupe lowo awon onibara,osise atawon afenifere fun aduroti lati odun metala seyin,ko sai dupe lowo ijoba apapo fun igbagbo ti won ni lori ileese naa to si tun ti seleri pe oun atawon osise oun ko ni i ja awon onibara won kule lailai.
Ileese Adron to je ileese akoko lo n lewaju laarin awon akeegbe e ninu ka ta ile lona irorun ,ti ileese yii si ti so opo di onile lori nitori aye wa lati sanwo diedie.
Opo ebun lawon onibara won ma n je pelu paapaa lasiko awon poposinsin odun,bee lo je pe gbogbo ibi ti won ni ile si ni,ina wa,ona geerege,omi to dara,eto aabo,ileewe gidi,ibi igbafe to rewa atawon ohun amayederu wa fun igbadun awon to ba ra ile ati ilẹ nileeṣẹ wọn.
Boya iwọ fẹ mọ si i nipa ileeṣẹ ADRON tabi o fẹ ra ilẹ,tete kan si eyikeyi ọfiisi wọn to ba wa nitosi ọdọ ẹ.

No comments:
Post a Comment