Awon ibeji'Jones'sekojade orin 'ṣẹkẹrẹ mi da ?ni ọjọ monde tọpọ awọn ololufẹ wọn si wa nikalẹ lati ba wọn ṣajọyọ ,bẹẹni wọn ṣafihan awọn iṣẹ wọn gẹgẹ bii telọ to moye(fashion show)
Won tun sajoyo odun ajinde Jesu olugbala,ọpọ awọn ololufẹ wọn bii,gbajumọ sọrọsọrọ ori redio nni,Dọkita Olutayọ Ṣomide,Pasitọ Ayọ Adefarasin,Aarẹ Afẹfẹ ọrọ,Oloye Abbey Fagbọrọ atawọn Ọba alade nilẹ yoruba.












No comments:
Post a Comment