Lasiko ọdun ajinde,ileeṣẹ ADRON ṣeto ẹbun fawọn onibara wọn. - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Sunday, April 20, 2025

Lasiko ọdun ajinde,ileeṣẹ ADRON ṣeto ẹbun fawọn onibara wọn.


Toyin Agbọlade
Odu ni ileeṣẹ ADRON ninu tita ilẹ lọna irọrun fawọn onibara wọn,ileeṣẹ naa ki n ṣaimọ foloko rara.
Ọna irọrun lati ra ilẹ nileeṣẹ ADRON lasiko ọdun ajinde Jesu Kristi tun ti wa bayii to si jẹ pe,aye wa lati sanwo diẹdiẹ ti ẹdinwo tun wa lori awọn ilẹ naa pẹlu ẹbun atata bii,amohunmaworan,ẹrọ ilọṣọ,ẹrọ amu omi tutu,ẹrọ ifatẹgun atọpọ ẹbun tabua.
Ilẹ wọn wa kaakiri origun mẹrin Orilẹ ede yii bii,Ṣimawa,Agbadarigi(Badagry)Ibadan,Abeokuta,Ẹdẹ,Iliṣan,Ijẹbuode,Abuja,Nasarawa,Papalanto,Ikorodu.
Boya iwọ fẹ jẹ ninu anfaani to n lọ lọwọ nileeṣẹ ADRON lati le ra ilẹ lọna irọrun ki o si di onile lori lasiko ọdun ajinde yii,tete kan si ọkan ninu ọfiisi wọn to ba wa nitosi ọdọ ẹ.

No comments:

Post a Comment

Pages