Opo awon eeyan pataki lawujo bii,Olugbaye Wasiu Ria,Alaaji Ahmad Alawiye,Alaaja Diamond,Alaaja Otibiya.
Awon borokini ati eeyan pataki lawujo lo pejupese sinu gbongan nla kan nilu Eko lasiko ti gbajumo oseretiata ,Ajoke Taiwo Ajedunni sekoja fiimu e to pe akole e ni'Ajedunni.
No comments:
Post a Comment