Omodekunrin kan ni Adugbo Ayegbami ,Ijebu igbo wa oko wo ile onile - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

I

Thursday, August 14, 2025

Omodekunrin kan ni Adugbo Ayegbami ,Ijebu igbo wa oko wo ile onile

Ariwo Olorunseun lawon tori isele to sele nilu Ijebu igbo npa lasiko ti odomodekunrin eni odun metadinlogun wa oko sugbon ti oko naa ya wonu ile onile,a gbo pe,okada lo pewo fun sugbon ti emi enikeni ko sonu

No comments:

Post a Comment

Pages