Lateef Adeola Okunola,egbon ObaOrin Saheed Osupa lo n sojo ibi loni in - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Tuesday, September 30, 2025

Lateef Adeola Okunola,egbon ObaOrin Saheed Osupa lo n sojo ibi loni in

Gbogbo ayajo ojo kini osu kewa ni ojo ibi,egbon Saheed Osupa Oba Orin,Alaaji Lateef Okunola,awon ololufe re si ti n ki omo bibi ilu Ibadan naa ku oriire ayeye orikadun.
Orile ede Canada ni Libra fi sebugbe nibe lo si ti n se daadaa,adura wa ni pe,emi e a sopo odun laye ninu owo ati alaafia,api baide Libra .

No comments:

Post a Comment

Pages