Aare Adetola ti wa so pe kawon olugbe orile ede Naijiria nigbagbo pe laipe ohun to le si maa ro,beeni ireti wa pe,ojo ola orile ede yii yoo dara,adura ati suuru ni oro naa gba.
Oludasile ileese Adron,Aare Adetola Emmanuelking ti ki gbogbo omo bibi Orile ede yii ati Aare Bola Ahmed Tinubu ku oriire ayeye odun marundinlaadorin (65)ti a gba ominira.
No comments:
Post a Comment