Oni gan an ni ojo ibi e,Mama Mistura,Momsy Ganiu,Mummy Rofiat adura ti wa ni pe,emi yin a sopo odun laye ninu owo ati alaafia
Odu ni Alaaja Basirat Iyabode laarin awon to n jo fawon olorin beeni mama yii tun ma n se owo lode ariya,opo olorin bii Wasiu Ayinde,Sefiu Alao,Shina Akanni,Wasiu Alabi,Abass Obesere ni omo bibi ipinle Ogun yii ti jo fun beeni o ma n se owo lode ariya won.
No comments:
Post a Comment