Waka Queen,Alaaja Ibiwunmi Salawa lo n sojo ibi loni in - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, May 5, 2026

Waka Queen,Alaaja Ibiwunmi Salawa lo n sojo ibi loni in

Gbogbo ojo karun un,osu karun un ni ayajo ojo ibi mama daadaa,agba oje olorin waka nni,Alaaja Ibiwunmi Salawa Abeni.
Opo awon ololufe e ni won ti n ki i kaakiri agbaye ,adura tiwa ni pe,emi mama a sopo odun laye ninu alaafia,owo ati ilera pipe,api baide tuu yuuuu mama tiwa.

No comments:

Post a Comment

Pages